Sapphire Asked: July 27, 2020 In: General Oriki Ake Abeokuta 1k Yhhhhhjjjffghjjnjkkkjbb Share Facebook You must be logged in to Answer this question! kindly login here or sign up here 1 Answer Voted chrisbillakings 2020-07-28T13:48:34+00:00 Added an answer on July 28, 2020 at 1:48 pm V Oriki of Ake (Abeokuta) Omo Ara ake majo, majo jo lofa, jojo lofa gbogbo dindin eni. Omo ajo gberu ma majo gbeko nitori eru nii sini, Eko kii sin'yan Omo oloka meridin logun omo elere mefa omo boba le peja ko peja omo boba leparo ko paro ogongon lo gbodopa omo alake mesi ara ake majo arake majo o Deleted
Oriki of Ake (Abeokuta)
Omo Ara ake majo, majo jo lofa,
jojo lofa gbogbo dindin eni.
Omo ajo gberu ma majo gbeko
nitori eru nii sini,
Eko kii sin'yan
Omo oloka meridin logun
omo elere mefa
omo boba le peja ko peja
omo boba leparo ko paro ogongon lo gbodopa omo alake mesi ara ake majo arake majo o